Posts

Showing posts from July, 2015

O fun mi l'edidi (He gave me a promise - Yoruba Hymn)

1. O fun mi l'edidi, Gbese nla ti mo je B'O ti fun mi,O si rerin Pe, ”Mase gbagbe mi!" 2. O fun mi l'edidi, O San gbese nla naa B'O ti fun mi osi rerin Wipe, "Maa ranti mi" 3. Ngo p'edidi naa mo Bi' gbese tile tan O nso Ife eniti o San Gbese nla naa fun mi 4. Mo wo,mo si rerin, Mo tun wo, mo sokun, Eri Ife Re si mi ni, Ngo toju Re titi 5. Ko tun s'edidi mo, Sugbon iranti ni! Pe gbogbo gbese nla mi ni Emmanueli san